Isikiẹli 14:18 BIBELI MIMỌ (BM)

bí àwọn ọkunrin mẹta náà bá tilẹ̀ wà níbẹ̀, bí èmi OLUWA ti wà láàyè, wọn kò ní lè gba ọmọkunrin tabi ọmọbinrin wọn là. Ara wọn nìkan ni wọn yóo lè gbàlà.

Isikiẹli 14

Isikiẹli 14:10-23