Isikiẹli 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mejeeji yóo jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Irú ìyà kan náà ni n óo fi jẹ wolii alára ati ẹni tí ó lọ wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀.

Isikiẹli 14

Isikiẹli 14:2-11