Isikiẹli 13:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ kò ní ríran èké mọ́, ẹ kò sì ní woṣẹ́ mọ́. N óo gba àwọn eniyan mi lọ́wọ́ yín, nígbà náà, ni ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Isikiẹli 13

Isikiẹli 13:14-23