Isikiẹli 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ya ìbòjú yín kúrò, n óo gba àwọn eniyan mi lọ́wọ́ yín. Wọn kò ní jẹ́ ohun ọdẹ lọ́wọ́ yín mọ́, ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.’

Isikiẹli 13

Isikiẹli 13:17-23