Isikiẹli 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún àwọn tí wọn ń kun odi náà ní ọ̀dà pé, òjò ńlá ń bọ̀, yìnyín ńlá yóo bọ́, ìjì líle yóo jà.

Isikiẹli 13

Isikiẹli 13:8-13