Isikiẹli 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbé ẹrù rẹ lé èjìká níṣojú wọn, kí o sì jáde ní òru. Fi nǹkan bojú rẹ kí o má baà rí ilẹ̀, nítorí pé ìwọ ni mo ti fi ṣe àmì fún ilé Israẹli.”

Isikiẹli 12

Isikiẹli 12:1-10