Isikiẹli 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Kó ẹrù rẹ jáde lójú wọn ní ọ̀sán gangan kí ìwọ pàápàá jáde lójú wọn ní ìrọ̀lẹ́ bí ẹni tí ń lọ sí ìgbèkùn.

Isikiẹli 12

Isikiẹli 12:3-12