Isikiẹli 12:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, kí ló dé tí wọ́n máa ń pòwe ní ilẹ̀ Israẹli pé, ‘Ọjọ́ ń pẹ́ sí i, gbogbo ìran tí àwọn aríran rí sì já sí òfo.’

Isikiẹli 12

Isikiẹli 12:12-26