Isikiẹli 12:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, máa jẹun. Bí o tí ń jẹun lọ́wọ́, jẹ́ kí ọwọ́ rẹ máa gbọ̀n, kí o sì máa fi ìwárìrì ati ìbẹ̀rù mu omi rẹ.

Isikiẹli 12

Isikiẹli 12:11-19