Isikiẹli 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún wọn pé, ‘Èmi OLUWA Ọlọrun sọ pé àsọtẹ́lẹ̀ yìí ń bá àwọn olórí Jerusalẹmu ati àwọn eniyan Israẹli tí ó kù ninu rẹ̀ wí.’

Isikiẹli 12

Isikiẹli 12:3-18