Isikiẹli 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ko yín kúrò ninu ìlú yìí, n óo sì ko yín lé àwọn àjèjì lọ́wọ́. N óo sì ṣe ìdájọ́ yín.

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:1-11