Isikiẹli 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, àwọn òkú yín tí ẹ dà sí ààrin ìlú yìí ni ẹran, ìlú yìí sì ni ìkòkò, ṣugbọn n óo mu yín kúrò láàrin rẹ̀.

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:1-11