Isikiẹli 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan lára àwọn Kerubu náà na ọwọ́ sí inú iná tí ó wà láàrin wọn, ó bù ú sí ọwọ́ ọkunrin aláṣọ funfun náà. Ọkunrin náà gbà á, ó sì jáde.

Isikiẹli 10

Isikiẹli 10:1-8