Isikiẹli 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn wọnyi ni àwọn ẹ̀dá alààyè tí mo rí lábẹ́ Ọlọrun Israẹli ní etí odò Kebari. Mo sì mọ̀ pé Kerubu ni wọ́n.

Isikiẹli 10

Isikiẹli 10:13-22