Isikiẹli 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rí kinní kan lókè awọsanma tí ó wà lórí wọn, ó dàbí ìtẹ́ tí a fi òkúta safire ṣe; mo sì rí kinní kan tí ó dàbí eniyan, ó jókòó lórí nǹkankan bí ìtẹ́ náà.

Isikiẹli 1

Isikiẹli 1:17-27