Isikiẹli 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

(Àgbá mẹrẹẹrin ní irin tẹẹrẹtẹẹrẹ tí ó so ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn pọ̀). Wọ́n ga, wọ́n ba eniyan lẹ́rù. Àwọn àgbá mẹrẹẹrin ní ojú yíká wọn.

Isikiẹli 1

Isikiẹli 1:10-27