Ìfihàn 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eṣú wọnyi dàbí àwọn ẹṣin tí a dì ní gàárì láti lọ sójú ogun. Adé wà ní orí wọn tí ó dàbí adé wúrà. Ojú wọn dàbí ojú eniyan.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:5-12