Ìfihàn 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

A kò gbà pé kí wọ́n pa wọ́n, oró ni kí wọ́n dá wọn fún oṣù marun-un, kí wọ́n dá wọn lóró bí ìgbà tí àkeekèé bá ta eniyan.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:1-13