Ìfihàn 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Iye àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣin jẹ́ ẹgbẹẹgbẹrun lọ́nà ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000,000). Mo gbọ́ iye wọn.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:13-18