Ìfihàn 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ní ìrù bíi ti àkeekèé tí wọ́n fi lè ta eniyan. A fún wọn ní agbára ninu ìrù wọn láti ṣe eniyan léṣe fún oṣù marun-un.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:5-17