Ìfihàn 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá ń kígbe pé, “Ti Ọlọrun wa tí ó jókòó lórí ìtẹ́, ati ti Ọ̀dọ́ Aguntan ni ìgbàlà.”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:9-17