Ìfihàn 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tú èdìdì karun-un, ní abẹ́ pẹpẹ ìrúbọ, mo rí ọkàn àwọn tí a ti pa nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọrun ati nítorí ẹ̀rí tí wọ́n jẹ́.

Ìfihàn 6

Ìfihàn 6:8-17