Ìfihàn 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ẹṣin mìíràn bá yọ jáde, òun pupa. A fi agbára fún ẹni tí ó gùn ún láti mú alaafia kúrò ní ayé, kí àwọn eniyan máa pa ara wọn. A wá fún un ní idà kan tí ó tóbi.

Ìfihàn 6

Ìfihàn 6:1-11