Ìfihàn 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá rí ẹṣin funfun kan. Ẹni tí ó gùn ún mú ọrun ati ọfà lọ́wọ́. A fún un ní adé kan, ó bá jáde lọ bí aṣẹ́gun, ó ń ṣẹgun bí ó ti ń lọ.

Ìfihàn 6

Ìfihàn 6:1-3