Ìfihàn 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rí i nígbà tí ó tú èdìdì kẹfa pé ilẹ̀ mì tìtì. Oòrùn ṣókùnkùn, ó dàbí aṣọ dúdú. Òṣùpá wá dàbí ẹ̀jẹ̀.

Ìfihàn 6

Ìfihàn 6:4-17