Ìfihàn 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sì rí angẹli alágbára kan tí ń ké pẹlu ohùn rara pé, “Ta ni ó yẹ láti ṣí ìwé náà, ati láti tú èdìdì rẹ̀?”

Ìfihàn 5

Ìfihàn 5:1-9