Ìfihàn 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀dá alààyè mẹrin náà bá dáhùn pé, “Amin!” Àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun sì dojúbolẹ̀, wọ́n júbà Ọlọrun.

Ìfihàn 5

Ìfihàn 5:5-14