Ìfihàn 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ẹ̀dá alààyè mẹrin náà bá fi ògo, ọlá ati ìyìn fún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́, ẹni tí ó wà láàyè lae ati laelae,

Ìfihàn 4

Ìfihàn 4:4-11