Ìfihàn 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn o ní àwọn díẹ̀ ninu ìjọ Sadi tí wọn kò fi èérí ba aṣọ wọn jẹ́. Wọn yóo bá mi kẹ́gbẹ́ ninu aṣọ funfun nítorí wọ́n yẹ.

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:3-5