Ìfihàn 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá ṣẹgun ni n óo jẹ́ kí ó jókòó tì mí lórí ìtẹ́ mi, gẹ́gẹ́ bí Èmi náà ti ṣẹgun, tí mo jókòó ti baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:14-22