Ìfihàn 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jí lójú oorun! Fún àwọn ohun tí ó ṣẹ́kù ní okun, nítorí àwọn náà ń kú lọ. Nítorí n kò rí iṣẹ́ kan tí o ṣe parí níwájú Ọlọrun mi.

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:1-10