Ìfihàn 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí mo bá fẹ́ràn ni mò ń bá wí, àwọn ni mò ń tọ́ sọ́nà. Nítorí náà ní ìtara, kí o sì ronupiwada.

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:13-22