Ìfihàn 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ iṣẹ́ rẹ. Mo mọ̀ pé o kò gbóná, bẹ́ẹ̀ ni o kò tutù. Ninu kí o gbóná tabi kí o tutù, ó yẹ kí o ṣe ọ̀kan.

Ìfihàn 3

Ìfihàn 3:11-16