Ìfihàn 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi Johanu ni mo gbọ́ nǹkan wọnyi, tí mo sì rí wọn. Nígbà tí mo gbọ́, tí mo sì rí wọn, mo dojúbolẹ̀ níwájú angẹli tí ó fi wọ́n hàn mí.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:1-9