Ìfihàn 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní sí ègún mọ́.Ìtẹ́ Ọlọrun ati ti Ọ̀dọ́ Aguntan yóo wà níbẹ̀. Àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo máa sìn ín.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:1-6