Ìfihàn 22:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n bá fọ aṣọ wọn ṣe oríire. Wọn óo ní àṣẹ láti dé ibi igi ìyè, wọn óo sì gba ẹnu ọ̀nà wọ inú ìlú mímọ́ náà.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:11-17