Ìfihàn 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá ṣẹgun ni yóo jogún nǹkan wọnyi. N óo máa jẹ́ Ọlọrun rẹ̀, òun náà yóo sì máa jẹ́ ọmọ mi.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:5-17