Ìfihàn 21:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo máa rìn ninu ìmọ́lẹ̀ rẹ̀. Àwọn ọba ilé-ayé yóo mú ọlá wọn wá sinu rẹ̀.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:16-27