Ìfihàn 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkúta iyebíye ni wọ́n fi mọ odi náà. Wúrà ni gbogbo ìlú náà tí ó mọ́ gaara bíi dígí.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:16-21