Ìfihàn 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kọ ìwé yìí sí angẹli ìjọ Simana:“Báyìí ni ẹni kinni ati ẹni ìkẹyìn wí, ẹni tí ó kú, tí ó tún wà láàyè:

Ìfihàn 2

Ìfihàn 2:1-11