Ìfihàn 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo ní nǹkan wí sí ọ. O ti kọ ìfẹ́ tí o ní nígbà tí o kọ́kọ́ gbàgbọ́ sílẹ̀.

Ìfihàn 2

Ìfihàn 2:1-8