Ìfihàn 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kọ ìwé yìí sí ìjọ Tiatira pé:“Ọmọ Ọlọrun, ẹni tí ojú rẹ̀ dàbí ọwọ́ iná, tí ẹsẹ̀ rẹ̀ ń dán bí idẹ.

Ìfihàn 2

Ìfihàn 2:10-20