Ìfihàn 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

A fún un ní aṣọ funfun tí ń dán, tí ó sì mọ́. Aṣọ funfun náà ni iṣẹ́ òdodo àwọn eniyan Ọlọrun.”

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:1-15