Ìfihàn 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún gbọ́ ohùn kan bí ohùn ọ̀pọ̀ eniyan, ati bí ìró ọpọlọpọ omi, ati bí sísán ààrá líle, ohùn náà sọ pé, “Haleluya! Nítorí Oluwa Ọlọrun wa, Olodumare jọba.

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:1-11