Ìfihàn 19:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun náà ati àwọn ẹ̀dá alààyè mẹrin náà bá dojúbolẹ̀, wọ́n júbà Ọlọrun tí ó jókòó lórí ìtẹ́. Wọ́n ní, “Amin! Haleluya!”

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:1-14