Ìfihàn 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ogun ọ̀run ń tẹ̀lé e, wọ́n gun ẹṣin funfun. Aṣọ tí wọ́n wọ̀ funfun, ó sì mọ́.

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:6-21