Ìfihàn 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba ayé ati àwọn tí wọ́n ti bá a ṣe àgbèrè, tí wọ́n ti ń bá a jayé yóo sunkún, wọn óo ṣọ̀fọ̀ lé e lórí nígbà tí wọ́n bá rí èéfín iná tí ń jó o.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:6-14