Ìfihàn 18:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu rẹ ni a ti rí ẹ̀jẹ̀ àwọn wolii ati ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan Ọlọrun, ati gbogbo àwọn ẹni tí wọ́n pa lórí ilẹ̀ ayé.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:15-24