Ìfihàn 18:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ní, “Èso tí o fẹ́ràn kò sí mọ́, gbogbo ìgbé-ayé fàájì ati ti ìdẹ̀ra ti bọ́ lọ́wọ́ rẹ, o kò tún ní rí irú rẹ̀ mọ́.”

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:6-24