Ìfihàn 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn oníṣòwò ayé yóo sunkún, wọn yóo ṣọ̀fọ̀ lé e lórí, nítorí wọn kò rí ẹni ra ọjà wọn mọ́; àwọn nǹkan bíi:

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:7-18